Strongest Teeth: Tajudeen ní èèyàn ló kù tí òun fẹ́ máa fi eyín gbé

  • Yemisi Oyedepo
  • Broadcast Journalist
Àkọlé fídíò,

Strongest Teeth: Tajudeen ní èèyàn ló kù tí òun fẹ́ máa fi eyín gbé

Ara kii tan nile alara, bẹẹ si ni ẹni ti ko ba de oko baba ẹlomiran ri, ni yoo ni oko baba oun lo tobi ju.

Ọkunrin kan ree, Tajudeen Olisa, ti wọ̀n n pe ni Taju Eleyin idan, to n lo eyin rẹ lati maa gbe awọn ẹru to wuwo bii apo irẹsi nla, ẹrọ amunawa jẹnẹratọ, tabili meji papọ, ati simẹnti, to si tun n fi eyin rẹ yii si agolo nla bii ọbẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ, Tajudeen, ẹni to ni eeyan lo ku fun oun bayii lati gbe, tun fikun pe, oun ko lo oogun ibilẹ rara, lati mu ki eyin oun lee ni agbara lati gbe ẹru to ba wuwo.

Producer Yemisi Oyedepo ati Bayo Odukoya