Fadeyi Oloro: Ọfọ̀, àyájọ́ kò ràn án lọ́jọ́ tí 'ṣó o láyà' bá a lálejò

Fadeyi Oloro: Ọfọ̀, àyájọ́ kò ràn án lọ́jọ́ tí 'ṣó o láyà' bá a lálejò

Eto 'Ṣó o láyà' lati BBC News Yoruba ni eto ti a ti maa n gbe awọn ibeere nipa aṣa, ede, iṣe ati ọrọ to n lọ ni Yoruba ka iwaju awọn eekan oṣere.

Lọtẹ yii, ẹja nla ni awọn eto yii gbe lodo.

eekan oṣere tiata, Ọgbẹni Ojo Arowoṣafẹ, ti ọpọ mọ si Fadeyi oloro ni ọpọn sun kan.

Atogede, atayajọ ni baba fi dahun ibeere wa gbogbo.

Amọṣa, aigbọfa la n woke, ifa kan ko si ni para