Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ to yẹ ló ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́

Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ to yẹ ló ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́

Laye ọjọsi, ere itage jẹ gbajugbaja lawujọ awọn onitiata lorilẹede Naijiria.

Ọpọlọpọ awọn ọjọgbọn lere tiata lo si ti n pariwo pe eku ko ke bi eku mọ lori ipa ti tiata n ko lori idagbasoke awujọ.

Alagba Peter Fatomilsla, ọkan lara awọn odu elere tiata lorilẹede Naijiria, toun pẹlu kopa lasiko ere itage ṣalaye ohun to ṣẹlẹ ati ibi ti ọrọ ti wọ wa.