Coronavirus Outbreak: Ijọba ìpínlẹ̀ Ogun dá àwọn ọlọpàá sita lati dẹkun ipéjọpọ

Ní ìpínlẹ̀ Ogun, ọpọ lo keti ọgbọin si àṣẹ ijọba to ni kí ẹnikeni ma lọ si ibi ipéjọpọ ti ènìyàn ba ti ju ààdọta lọ.

Yoruba bọ wọ́n ni ọ̀rọ̀ sùnukùn , ojú sùnùkùn la fi n wòó, eyi lo mu ki ìjọba sda àwọn ọlọpàá sita.

Àwọn ọlọpàá se abẹwò si àwọn ilé ijọsin lóríṣirísi ti wọ́n si ṣe ẹtọ ni ibi ti wan ti ri pe èrò pọ ju bo se lọ.

Bakan náà lọ́mọ́ se sori ni ni ìpínlẹ̀ Eko, sùgbọ́n ilé ijo ni àwọn alamoju to ijọba lọ ti wọ́n si gbé àwọn to taṣẹ agẹrẹ sofin pa