Ǹjẹ́ oòrùn tàbí oru leè pa àrùn Coronavirus bí?

Ǹjẹ́ oòrùn tàbí oru leè pa àrùn Coronavirus bí?

Awọn kan ti n sọ lori itakun ayelujara pe oru tabi oorun lee pa kokoro aifojuri Coronavirus.

Ọpọ awọn elomiran lo si ti n pin iru iroyin bẹ to pẹlu awọn ẹbi ati ololufe wọn.

Eyii ti mu ki awọn ka bẹrẹ si ni sa ara wọn sinu oorun bi aṣọ tutu, pẹlu igbagbọ pe igbesẹ ọhun yoo dabo bo wọn lọwọ arun naa.

Ṣugbọn ọrọ ti ajọ elelto ilera lagbaye, WHO fi lede tako awọn iroyin wọnyi

BBC Yoruba tu pẹrẹperẹ bi ọrọ ọhun ṣe jẹ gan ninu fidio to wa loke yii.