Coronavirus pandemic: Toyin Abrahams ṣàlàyé pé ọ̀pọ̀ àhesọ ọ̀rọ̀ tí kò ní àǹfàní ló ń jáde nípa ààrùn Coronavirus

Coronavirus pandemic: Toyin Abrahams ṣàlàyé pé ọ̀pọ̀ àhesọ ọ̀rọ̀ tí kò ní àǹfàní ló ń jáde nípa ààrùn Coronavirus

Ọrọ arun coronavirus ti di eyi ti gbogbo agbaye n karamasiki rẹ bayii.

Oniruru awọn eekan ilu lo si ti sọrọ nipa rẹ.

Eyi ni ọrọ ti gbajumọ oṣere sinima lorilẹede Naijiria, Toyin Abraham sọ nipa rẹ.