Ọ̀dá owó ló sọ mi di alábárù, iṣẹ́ àbárù sàn ju olè jíjà lọ-Alábárù

Ọ̀dá owó ló sọ mi di alábárù, iṣẹ́ àbárù sàn ju olè jíjà lọ-Alábárù
Alabaru

Iṣẹ alabaru lee jẹ iṣẹ ti ọpọ ko mu lọkunkundun nitori oju ti awujọ fi n wo wọn. Amọṣa, bi eniyan ba wọ inu ọja lọ, yoo ri to lori awọn eeyan wọnyii ṣe n fara ṣiṣẹ ki wọn maa baa jale tabi wo ọwọ ọlọwọ jẹun.

Eyi ni itan ọkan lara awọn oṣiṣẹ amọrọaje duro deede naa ti aye n pe lalabaru.

Arabinrin yii sọ ohun ti oju n ri lẹnu iṣẹ naa ati ohun to sun oun gẹgẹ bii ẹnikan lati darapọ mọ iṣẹ abaru.