Coronavirus in Nigeria: Ǹjẹ́ irinṣẹ́ tó ń wo ara gbígbóná ''thermal'' lé sọ èèyàn ní coronavirus?

Coronavirus in Nigeria: Ǹjẹ́ irinṣẹ́ tó ń wo ara gbígbóná ''thermal'' lé sọ èèyàn ní coronavirus?

Ọkan lara awọn apẹẹrẹ aarun coronavirus ni ki ara eeyan maa gbona.

Ṣugbọn njẹ eyi tumọ si pe gbogbo ẹni ti ara wọn ba n gbona lo ni aarun covid-19 bi?

Rara o! Gẹgẹ bi ọrọ ti ajọ to n ri si eto ilera lagbaye, WHO ṣe sọ, irinṣẹ iṣegun oyinbo ''thermal'' ko le sọ bo ya eeyan ni aarun coronavirus.

Ẹ wo alaye lẹkunrẹrẹ ninu fidio yii.