Coronavirus cases in Africa: Ijọba ipinlẹ Oyo ti kọ ẹgbẹsan irẹsi to jẹ iranwọ ti ijọba apapọ fi ransẹ si wọn.

Coronavirus cases in Africa: Ijọba ipinlẹ Oyo ti kọ ẹgbẹsan irẹsi to jẹ iranwọ ti ijọba apapọ fi ransẹ si wọn.

Ijọba ipinlẹ Oyo ti sọ idi ti awọn fi kọ irẹsi to lẹ ti ẹgbẹsan ti ijọba apapọ fi ransẹ si wọn

Awọn alabojuto eto ounjẹ nipinlẹ Oyo ti wọn fi lede fun awọn ara ipinlẹ Oyo.

Wọn fi lede wi pe kokoro wa ninu irẹsi naa, ti o si fihan gbangba pe awọn ounjẹ naa ti bajẹ.

Bakan naa ni wọn fikun wi pe awọn ko binu si ijọba apapọ amọ ti wọn ba ni irẹsi miran to dara awọn yoo gba lọwọ wọn

Ẹkunrẹrẹ fidio naa ni eyi;