What did Buhari say about the lockdown: Awọn ọmọ Nàìjíríà káàkiri àgbáyé sọ ìrírí lábẹ́ àṣẹ kónílé-ó-gbélé

What did Buhari say about the lockdown: Awọn ọmọ Nàìjíríà káàkiri àgbáyé sọ ìrírí lábẹ́ àṣẹ kónílé-ó-gbélé

Kariaye laarun Coronavirus. Gbogbo orilẹede agbye lo fẹẹ tan de tan.

Ni bi a ṣe n sọrọ yii, o ti le ni miliọnu mẹta eeyan to ti ko aarun yii lagbaye.

Gbogbo agbaye lo si ti n gbe igbesẹ lori ọna ti yoo fi pari lọdọ wọn.

Awọn ọmọ Naijiria kaakiri agbaye ṣalaye ohun ti oju wọn ri ati boya inu wọn dun pe wọn ko si ni orilẹede Naijiria ni iru asiko yii.