Corornavirus: Ṣe lilo ìbọ̀wọ́ le dènà ààrùn Coronavirus
Corornavirus: Ṣe lilo ìbọ̀wọ́ le dènà ààrùn Coronavirus
O ṣeeṣe ki iwọ naa ti ri tabi gbọ nipa pé bi ènìyà ba ti lo ìbọ̀wọ́ ewu Corornavirus ti fòó.
Èyí kò rí bẹ́ẹ̀ ti ẹni náà kìí bá ti ṣe oṣisẹ ilera tabi awakọ, kóda lilo ìbọwọ́ tun le ṣe akóba fún ọ láti ma huwa aibikita níto ri pé o fi ibọwọ si ọwọ.
Nítori náà o ṣe pàtàkì láti maa fi ọṣẹ fọwọ́ lóòrèkóòrè, lati ri dáju pe o dáàbò bo ilé rẹ lọ́wọ́ ààrun Corornavirus
- Gómìnà Ṣèyí Mákindé ó ní ìdí tí òun kò fi leè ti ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pa nítorí COVID-19
- Ọlọ́run ló kọọ pé àwọn ọmọ mi yóò ṣiṣẹ tíátà, èmi kọ lo kàn-án nípa fún wọn - Ọga Bello
- Owó gọbọi wá nídìí oko-owo igbó gbingbin, Ìpínlẹ̀ Ondo kò ní pẹ gba àṣẹ láti gbin - Akeredolu
- Inú mi dùn pé àṣẹ kónílé-ó-gbélé kò bá mi ní Nàìjíríà-Àwọn ọmọ Nàìjíríà lágbáyé