Oman Slave: Ó pe mi kí n máa mu Gari ní Nàìjíríà ju ìlú yẹn lọ o

Oman Slave: Ó pe mi kí n máa mu Gari ní Nàìjíríà ju ìlú yẹn lọ o

Ohun taa jẹ, taa mu, taa fi r'ile aye gbe lo mu arabinrin yii ti a ko le fi oju rẹ han kuro ni Naijiria lọ gba iṣẹ ni orilẹede Oman.

Arabinrin yii s fun BBC pe jẹjẹ loun wa nilu wọn ti wọn sọ fun un pe iṣẹ wa ni orilẹede kan ti wọn yoo ti maa san owo to to igba miliọnu naira fun un.

"Bi kii ba ti ṣe iṣẹ aṣẹwo, o dara". Ni arabinrin yii fesi fun awọn aburo rẹ to ba a wa iṣẹ. O de 'bẹ tan lorin ba yipada.