Ṣé òótọ ni pé èèyàn leè kó Coronavirus láti ara aṣọ tàbí bàtà?

Ṣé òótọ ni pé èèyàn leè kó Coronavirus láti ara aṣọ tàbí bàtà?

Ọna kan gboogi ti arun Covid-19 fi n wọ ara eeyan ni lati ẹnu, imu tabi oju.

Awọn kan ti wa n bere pe n jẹ o ṣeṣẹ ki eeyan ko arun ọhun lati ara aṣọ tabi bata ti eeyan ba wọ.

Lootọ ni pe eeyan le ko arun Coronavirus lati ara ohun ti arun naa ba wa, bii ori tabili, aga iojoko tabi nnka mii.

Ṣugbọn ṣe o ṣeṣẹ ki eeyan lugbadi arun Coronavirus lati ara aṣọ tabi bata?

Ẹ wo fidio yii fun alaye ni kikun.