Nigeria movie industry: Àgbà òṣèré, Lere Paimo ní àìgbọràn ló ń da ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣèrè sinimá láàmú
Nigeria movie industry: Àgbà òṣèré, Lere Paimo ní àìgbọràn ló ń da ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣèrè sinimá láàmú
Agba oṣere lagbo tiata ati sinima ni Oloye Lere Paimọ, MFR tiọpọ mọ si 'Ẹda onile ọla', orukọ rẹ ko si lee parun ninu itan sinima ati tiata ni ilẹ Yoruba.
Lati inu awọn manigbagbe sinima bii 'Ogbori Ẹlẹmọṣọ' de Aṣiri nla' atawọn sinima miran, ni agba oṣere yii ti fi ara rẹ si aaye manigbagbe lọkan awọn ololufẹ sinima ati igbelarugẹ itan, aṣa ati iṣe Yoruba.
Amọṣa, ohun kan wa to n ks agba oṣere yii lominu nipa ipo ti agbo ere sinima ati tiata lorilẹede Naijiria, paapaa julọ ilẹ Yoruba wa bayii.
O ba BBC News Yoruba sọ diẹ nipa ọrọ ọhun. Abọ ree ninu ifọrọwanilẹwo yii o.
- 'Fásitì Nàìjíríà kò gbà mi wọlé ló mú mi sá lọ Ukraine, àmọ́ ohun tí ojú mi rí nínú ogun náà rèé kí ń tó sá wá Nàìjíríà'
- Àdó olóró búgbaàmù nílú Iware, èèyàn márùn-ún ti kú
- Bí mo ṣe rí ọ̀pọ̀ Mílíọ̀nù Nàírà tí mo sì dáà padà fún Ọlọ́pàá lọ́dún 1971 àmọ́ ǹkan t'íjọba sọ rèé - Baba Shonubi
- Àwọn ọ̀dọ́ ló leè gba Naijiria là kúrò ní oko ẹrú –Imam Akeugbagold