Nollywood stars: Àwọn èèkàn òṣèré sinimá ní Nàìjíríà jẹ́wọ́ ara wọn lórí fífi àmì ohùn sí ọ̀rọ̀ Yorùbá

Nollywood stars: Àwọn èèkàn òṣèré sinimá ní Nàìjíríà jẹ́wọ́ ara wọn lórí fífi àmì ohùn sí ọ̀rọ̀ Yorùbá

Wọn ni oogun ti a ko ba fi han ọmọ ẹni kii pẹ parun.

Ọpọ lo n kọminu lori ede Yoruba ati bi ti yoo de duro nigba ti a o ba fi ri asiko diẹ si.

Eyi lo mu ki ikọ BBC News Yoruba tọ diẹ lara awọn amuludun ti wọn n fojojumọ gbe sinima Yoruba jade pe, bawo ni lori fifi ami ohun si ọrọ Yoruba. Abọ wa niyi, Ẹ gbe e yẹwo.