Rape cases in Nigeria: Báyìí ni ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọmọnìyàn ṣe pè fún ìdájọ́ ikú fún àwọn afipábánilòpọ̀

Rape cases in Nigeria: Báyìí ni ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọmọnìyàn ṣe pè fún ìdájọ́ ikú fún àwọn afipábánilòpọ̀

Agbarijọpọ awọn ẹgbẹ ajafẹtọmọniyan bii mẹrinla ti koro oju si iwa ifipabanilopọ ati iṣekupani ti awọn obinrin n koju lawujọ.

Ninu ipade ni ilu Ibadan, awọn ẹgbẹ naa gbarata lori iwa ọdaran ti awọn amokunṣeka kan n hu si ọmọde ati awọn agba to jẹ obinrin.

Ohun to jẹ ẹgbẹ ajafẹtọmọniyan na logun julọ ni ọrọ iṣekupani ati ifipabanilopọ.

Ọkan lara awọn aṣoju ẹgbẹ naa, Arabinrin Grace Oluwatoye kesi ijọba ati awọn agbofinro lati bojuto wahala ti awọn ọmọbinrin n dojukọ lasiko yii.

Ẹ wo fidio yii fun ẹkunrẹrẹ.