Azeezat Shomuyiwa : Oyún oṣù méje ló wà nínú Azeezat, kí wọ́n tó f'òkúta fọ́ ọ lórí pa

Azeezat Shomuyiwa : Oyún oṣù méje ló wà nínú Azeezat, kí wọ́n tó f'òkúta fọ́ ọ lórí pa

Lẹyin igbeyawo nilana Musulumi ti wọn n pe ni Nikkah, ireti Alfa Ridwan ati Iyawo rẹ Azeezat ni pe lẹyin oṣu mẹsan ki wọn wa ba wọn ṣe isọmọlorukọ, iyẹn 'suna'.

Asiko imuṣẹ ala rere yii n sun mọ dẹdẹ ni Alfa Ridwan ba ni ki iyawo rẹ o maa bọ nile wa bimọ sọdọ awọn obi oun lo ba di wi pe iroyin iku aya rẹ ni wọn fi ranṣẹ sii pada ni ilu Kano.

Hmmm...Eduwa ko ni jẹ ka kagbako o, ẹkunrẹrẹ itan awodamiloju yii la mu wa fun yin loni, ẹ wo fidio rẹ loke yii.