Kid boxer: Ọmọọba 'The Buzz' Larbie rèé, ọmọ ọdún méje tó ń fi ẹ̀ṣẹ́ dá bírà tó ju ọjọ́ orí rẹ̀

Kid boxer: Ọmọọba 'The Buzz' Larbie rèé, ọmọ ọdún méje tó ń fi ẹ̀ṣẹ́ dá bírà tó ju ọjọ́ orí rẹ̀

Awọn agba bọ wọn ni ọmọ to ba maa jẹ aṣamu, kekere lo ti n ṣẹnu ṣamuṣamu; eyi ni itan Ọmọọba 'The Buzz' Larbie to n ti kekere ṣe ohun ti agba ko lee ṣe lagbo ẹṣẹ kikan.