Yetunde Bakare dárà lórí ètò Ṣé o láyà, ẹ ràn án lọ́wọ́ nínú ìbéèrè tó ṣì
Yetunde Bakare dárà lórí ètò Ṣé o láyà, ẹ ràn án lọ́wọ́ nínú ìbéèrè tó ṣì
Ikoko dudu fẹyin ti igbo, Ta n mọ o?
Igbin ni idahun rẹ.
Eyi ati awọn ibeere miran ni BBC Yoruba beere lọwọ Yetunde Bakare to jẹ gbajugbaja oṣere Yollywood.
Orukọ miran wo ni Yoruba n pe kokoro èèrùn?
O ya ẹ gbiyanju ẹ wo!