South Korean Dogs: Wo bi ọbẹ̀ ẹran ajá ṣe dùn tó
South Korean Dogs: Wo bi ọbẹ̀ ẹran ajá ṣe dùn tó
"Bẹẹ ni, mo maa n jẹ ẹran aja".
Arabinrin yii to jẹ ọdọ ọmọ orilẹede South Korea ni ki lawọn eeyan n pariwo si lorii keeyan maa gbadun jijẹ ẹran aja.
O ni ni toun ẹran lẹran n jẹ, ẹran lasan si ni aja jẹ
"Ko yatọ si ẹran Maalu, Ẹlẹdẹ tabi Pẹpẹyẹ".
Gẹgẹ bi iye awọn to ni ẹran aja gẹgẹ bi nkan ọsun ṣe n pọ sii lorilẹede South Korea
Jíjẹ́ Vs sínsin ẹ̀ran Ajá Vs fífẹ́ ẹni tó ń jẹ ẹran Ajá? Ẹ wá mú ọ̀kan
Awọn ọmọ South Korea bọ sori gbagede eto kan naa lati tako ara wọn lorii boya o tọ lati maa jẹ ẹran ọsin ti eeyan fẹran gẹgẹ bi ọrẹ.
Awọn mii ni laye atijọ wọn maa n si aja fu jijẹ nibẹ ni ati pe aṣa ilẹ awọn ni.
Láàrọ̀ kùtùkùtù torí Ọlọ́run
Mo ríi lọ́jà tí àwọn kan sorí Ajá kodò láti tà a fún jíjẹ́, ẹ̀rù bà mí gidi gan
Awọn kan ko foju rere wo o.