Nigeria prison experience: Abass Owonikoko dèrò ẹ̀wọ̀n fún ọdún 27 torí ìwà ìpáǹle, kó tó gba kéú lọ́gbà ẹ̀wọ̀n

Nigeria prison experience: Abass Owonikoko dèrò ẹ̀wọ̀n fún ọdún 27 torí ìwà ìpáǹle, kó tó gba kéú lọ́gbà ẹ̀wọ̀n

Yoruba ni fi ọrẹ rẹ han mi, ki n sọ iru eeyan to jẹ nitori aguntan to ba n ba aja rin yoo jẹ igbẹ.

Bẹẹ ni ọrọ ri pẹlu ọkunrin kan, Abass Abiodun Owonikoko, tii se onisowo ounjẹ lọja Bodija nilu Ibadan.

Awọn isẹlẹ Kayeefi miran ti ẹ le nifẹ si:

Ija ni Owonikoko atawọn ọrẹ rẹ mẹrin miran lọ ja lẹyin eegun lọdun 1993, ti wọn si pa eeyan meji.

Eyi lo ba de ọgba ẹwọn, ti wọn fi dajọ iku fun, sugbọn ti gomina Ibikunle Amosun ba yi pada , to si gba idande lẹyin ọdun mẹtadinlọgbọn.

Inu ọgba yii lo wa to fi di imaamu, o keu, to si gba alukurani.

Àwọn ìtàn Mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ẹnu onikan la ti n gbọ kanun, ẹ gbọ ọrọ latẹnu ọkunrin yii funra yin.