Akomolede ati Aṣa: Mọ̀ síi nípa ìró afárànma àti agbárànmọ́ fáwẹ́ẹ̀lì Yorùbá

Akomolede ati Aṣa: Mọ̀ síi nípa ìró afárànma àti agbárànmọ́ fáwẹ́ẹ̀lì Yorùbá

Òfin mélòó ní o mọ̀ tí Àrànmọ́ Fáwẹ́ẹ̀lì Yorùbá gbọ́dọ̀ ní?

Akomolede ati Aṣa lori BBC Yoruba lo tun jade lonii.

Aranmọ Fawẹẹli ni olukọ to dantọ ni o n kọ wa bayii.

Alagba Oyewole Isaac lati ile ẹkọ Awaye Comprehensive Grammar School ni Ilẹ Oluji ni ipinlẹ Ondo ni olukọ wa lonii.

Agbara ti iro kọọkan ni lori ikeji rẹ wa lara ohun ti a n gbe yẹwo.

Eto yii jẹ ajóṣẹpọ ẹgbẹ Onimọ Yoruba, YSAN ati ti apapọ ẹgbẹ Akomolede ati Aṣa Yoruba ti Naijiria lapapọ.

Ofin to rọ mọ aran ma gbigba ati oriṣii Aranmọ mẹrin to wa wa lara koko ti a gbe yẹwo lonii pẹlu apẹẹrẹ.