Oluwo Jogbodo Orunmila: Ẹsẹ odù Ifa ló fi ṣúre fún ọmọ Nàíjíríà ní àyájọ́ ọdún tuntun

Oluwo Jogbodo Orunmila: Ẹsẹ odù Ifa ló fi ṣúre fún ọmọ Nàíjíríà ní àyájọ́ ọdún tuntun

Adura lọtun losi, ni mu ẹmi ẹda gun.

Ọpọ ojo adura lo ti n rọjo sori awọn ọmọ Naijiria lati ileesẹ BBC Yoruba lati igba ta ti wọnu ọdun tuntun 2021.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Nilana ti ibilẹ, Baba Awo, Oluwo Jogbodo Orunmila naa ree, to n rọjo adura sori awọn araalu gẹgẹ bii iwure ọdun tuntun.