
Anambra 2021 Election: Bí o ṣe le mọ ìbùdó ìdìbò rẹ̀ ní Anambra

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ti o ba jẹ oludibo nipinlẹ Anambra, to si fẹ kopa ninu eto idibo to n bọ yii, wo akọsil yii lati sedamọ ibudo idibo rẹ.
Eyi ni ko ni jẹ ko sina lasiko to ba n lọ dibo tabi ko lọ sibi ti ko yẹ.