Wo fidio ọmọbirin to n sunkun ẹjẹ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Wo bi ọmọbirin yii se n sun ẹjẹ

Nigba ti ọmọ ọdun mẹtala to man se iroyin fidio, Nikki Christou ba n sukun - ẹjẹ lo maa n da l’oju rẹ dipo omije. Nikki ni ailera to jọmọ bi ẹjẹ n tin san ninu isan, AVM, eleyi to maa n jẹ ko sunkun ẹjẹ ati sise okunfa ẹjẹ-dida to le la ẹmi lọ ati rirọlaparọlẹsẹ.

Related Topics