Buhari ba Aarẹ Xi ti China yọ

Buhari ba Aarẹ China, Xi Jinping yọ Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Buhari ba aarẹ China, Xi Jinping yọ

Aarẹ Naijiria, Muhammadu Buhari ti ba Aarẹ orilẹede China, Xi Jinping, yọ lori saa oye aarẹ tuntun ti igbim asofin ile rẹ fi jẹ.

Ninu iwe kan aarẹ Naijiria buwọlu funrarẹ, Buhari gb'oriyin fun ọgbọn ato oye aarẹ China.

Bakanaa Aarẹ Naijiria sọ wi pe yiyan ti wọn yan Aarẹ Xi s'afihan igbagbọ t'awọ eeyan orilẹede naa ni si.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ile igbimọ asofin Chin ati panupọ yan Xi Jinping l'aarẹ ni saa keji ọlọdun maarun

Buhari ni oun ni ireti wi pe ajọsepọ laaarin Naijiria ati China yoo ma pọ gẹgẹ bi oun ti lero wi pe ajọpọ China pẹlu Afrika yoo tun m agbopọn si.