Wo bi wọn ṣe n ṣ'ẹsin abalaye Yorùbá ni Brazil ati Cuba

A wọn aworan yii s'afihan bi wọb ti n ṣ'ẹsin abalaye Yorùbá l'oke okun.

Ẹlẹsin Iyemọja Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ẹlẹsin Yemanja (Iyemọja) kan fi asia orilẹede Brazil bora lori aga kan to wa l'eti odo saaju ki wọn to bẹrẹ ọdun Yemanja , ni eti odo Rio Vermelho ni Salvador, ipinlẹ Bahia, l'orilẹede Brazil, l'ọjọ keji osu keji, ọdun 2018. Yemanja, to jẹ oriṣa odo ninu ẹsin abalaye Yorùba, jẹ ọkan lara awọn oriṣa to gbajumọ ju ninu aṣa adulawọ l'orilẹede Brazil.
Awọn olujọsin n gbadura ni waju ojubọ kan ni eti odo Salvador, nipinlẹ Bahia, l'orilẹede Brazil nigba ọdun Yemanja (Iyemọja), oriṣa odo lati ẹsin abalaye Yoruba to jẹ ọkan lara awọn oriṣa to gbajumọ ju ninu aṣa awọn adulawọ nilẹ Brazil. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Awọn olujọsin n ṣure ni waju ojubọ kan ni eti odo Salvador, nipinlẹ Bahia, l'orilẹede Brazil nigba ọdun Yemanja (Iyemọja), oriṣa odo lati ẹsin abalaye Yorùbá to jẹ ọkan lara awọn oriṣa to gbajumọ ju ninu aṣa awọn adulawọ nilẹ Brazil.
Awọn onigbagbọ ninu ẹsin Yemanja (Iyemọja) kojọ pọ si eti omi ni Salvador lati ṣe ayẹyẹ ọjọ Yemanja, oriṣa omi ninu aṣa Yorùbá to si jẹ ọkan lara awọn oriṣa to gbajumọ ju ninu aṣa adulawọ ilẹ Brazil Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Awọn onigbagbọ ninu ẹsin Yemanja (Iyemọja) kojọ pọ si eti omi ni Salvador lati ṣe ayẹyẹ ọjọ Yemanja, oriṣa omi ninu aṣa Yorùbá to si jẹ ọkan lara awọn oriṣa to gbajumọ ju ninu aṣa adulawọ ilẹ Brazil
Awọn ẹlẹsin abalaye Yorùbá ninu awọn adulawọ Cuba n se etutu nigba 'lẹta ọdun'-to maa n ka gbogbo asọtẹlẹ nnkan ti yoo sẹlẹ ninu ọdun silẹ, nigboro Havana l'ọjọ keji osu kinni ,ọdun 2018. Asọtẹlẹ naa maa n waye ni lorin nnkan ti ifa ba sọ fun awọn babalawo wọn. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Awọn ẹlẹsin abalaye Yorùbá ninu awọn adulawọ Cuba n se etutu nigba 'lẹta ọdun'-to maa n ka gbogbo asọtẹlẹ nnkan ti yoo sẹlẹ ninu ọdun silẹ, nigboro Havana l'ọjọ keji osu kinni ,ọdun 2018. Asọtẹlẹ naa maa n waye ni lori nnkan ti ifa ba sọ fun awọn babalawo wọn.
T'oun ti pe wọ jina si ilẹ Yorùbá, awọn ẹlẹsin abalaye Yorùbá nigbagbọ ninu ẹsin naa Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán T'oun ti pe wọn jina si ilẹ Yorùbá, awọn ẹlẹsin abalaye Yorùbá nigbagbọ ninu ẹsin naa gẹgẹ bi awọn to wa ninu aworan ti wọn ya l'orilẹede Cuba yii
Awọn eeyan n sure l'eti omi Rio Vermelho ni Salvador to wa ni ipinlẹ Bahia pẹlu igbagbọ wipe waju Yemanja (Iyemọja) n gbọ nnkan ati ireti pe yoo da wọn lohun Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Awọn eeyan n sure l'eti omi Rio Vermelho ni Salvador to wa ni ipinlẹ Bahia pẹlu igbagbọ wipe Yemanja (Iyemọja) n gbọ nnkan ti wọn sọ ati ireti pe yoo da wọn lohun
Awọn eeyan ne ṣ'etutu nigba ti wọn s'ọdun Yemanja (Iyemọja) l'eti omi Vernelho nipinlẹ Bahia to wa ni orilẹede Brazil Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Awọn eeyan ne ṣ'etutu nigba ti wọn s'ọdun Yemanja (Iyemọja) l'eti omi Vernelho nipinlẹ Bahia to wa ni orilẹede Brazil

Getty Images ni orisun awọ aworan naa

Ní àyíká BBC