Ẹlẹ́wọ̀n: Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni mo ti kàwé yege ní ìdánwò Jamb

Ẹlẹ́wọ̀n: Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni mo ti kàwé yege ní ìdánwò Jamb

Ẹlẹ́wọ̀n kan ti ní inú ọgbà ni òun ti s‘orí rere nítori ibẹ̀ ni òun ti kàwé yege ìdánwò Jamb.

O ní nínú àwọn ẹlẹ́wọ̀n méjìlá táwọn jọ se ìdánwò náà, òun ni òun léwájú gbogbo wọn pẹ̀lú máákì 248.

Ẹlẹ́wọ̀n náà ní isẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ ni òun fẹ́ se, tó sì bẹ̀bẹ̀ fún ìsíjú àánú woni.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: