G-string tàbí Hip-star, èwo lo fẹ́ràn jù?
G-string tàbí Hip-star, èwo lo fẹ́ràn jù?
Orísirísi pátá ló wà, tó gbayi fáwọn obìnrin, pàápàá àwọn ìyàwó ọ̀sìngí láti wọ̀ sára.
Bí Thong se wà, ni G-string, Hip-star,Brief àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ wà,
Èwo wá lo fẹ́ràn nínú wọn láti wọ̀ ?