Àpọ̀jù òògùn ikọ́ olómi Codeine, ìbẹ̀rẹ̀ wèrè
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Fídíò òògùn ikọ́ olómi: Codeine dùn lóòtọ́ àmọ́ ewu ni

Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ ní orílẹ̀èdè Nàíjíríà ni ìwádìí abẹ́lẹ̀ tí iléesẹ́ BBC se ti fihàn pé ewu ńlá ń bẹ nínú mímu àpọ̀jù Òògùn ikọ́ olómi tó ní èròjà Codeine nínú.

Fídíò náà, tó bẹ̀rẹ̀ láti ìlú Kano dé Ìlọrin tú àsírí tó wà nínú títà àti títa Òògùn ikọ́ olómi Codeine ní Nàíjíríà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: