George Bush àgbà kúrò nílé ìwòsàn lẹ́yìn àìsàn ráńpẹ́

George Bush àgbà Image copyright @Georgebushtwitter
Àkọlé àwòrán Àgbà ṣòró ó dà, pàápàá lẹ́yìn ikú aya èni

George Bush àgbà di èrò ilé ìwòsàn lọ́jọ́ kejì tó sìnkú aya rẹ̀, Barbara tí wọn jọ gbé pọ̀ fún odidi ọdún mẹ́tàléláàdọ́rin

Ilé iṣẹ́ George Bush àgbà ti fi àtẹ̀jáde síta pé, àwọn aláṣẹ ilé ìwòsàn Methodist Hospital ti fi ààrẹ àná fún ilẹ̀ America sílẹ̀'.

O jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlẹláàdọ́rún.

Wọn ni ara George Bush àgbà ti bàlẹ̀. O tí ń bà àwọn ẹbí àti olùtọ́jú rẹ̀ nílé ìwòsàn sọ̀rọ̀ bí ó ti yẹ

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: