Wo ohun àràmàndà tí àwọn olósèlú máa ń ṣe lásìkò ìbò

FAYOSE Image copyright Facebook
Àkọlé àwòrán Ni idibo ọdun 2015, Fayọse pin adiye fun awọn eniyan.

Eto oselu lorilẹ-ede Naijiria jẹ ọkan gboogi ninu awọn ohun ti o ni i se pẹlu igbe aye awọn eniyan lawujọ.

Lọpọ igba, awọn oloṣelu máa n lo asiko idibo lati fi ara han awọn ara ilu gẹgẹ bi ẹni pe awọn naa jẹ ikan kan naa pẹlu wọn nipa ṣiṣe ohun aramanda.

Image copyright FACEBOOK
Àkọlé àwòrán Oludije si ipo gomina ni Ọṣun labẹ ẹgbẹ oselu SDP ni ọdun 2018 n jẹ agbado sisun lori ọkọ ayọkẹlẹ lasiko ipolongo.

Ọpọlọpọ gomina ni ẹkun iwọ oorun guusu lorilẹ-ede Naijria ni wọn ti fi igba kan lọ si aarin ilu lati lọ ba awọn eniyan ṣiṣẹ tabi ran wọn lọwọ, tabi ki wọn jẹun pẹlu wọn ni ita gbangba.

Awọn aworan nibi ti awọn oloselu ti n e nkan aramanda

Image copyright Facebook
Àkọlé àwòrán Oludije si ipo sẹnetọ ni ipinlẹ Kaduna pin redio fun awọn eniyan bi o tilẹ je pe o ni ko ni i se pẹlu oselu, amọ fun Ayajọ Ọjọ Radio lagbaye.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionẸ wo ọ̀nà àbáyọ tí àwọn olùdíje gómìnà pèsè sí ìṣòro Eko
Image copyright FACEBOOK
Àkọlé àwòrán Gomina Rauf Arẹgbesọla ni ọdun 2014 wọ asọ ile iwe awọn alakọbẹrẹ lati polongo idibo fun saa keji gẹgẹ bi gomina Ọṣun.
Image copyright Nairaland
Àkọlé àwòrán Gomina ipinlẹ Ondo pin burẹdi fun awọn eniyan saaju idibo sipo gomina ni ipinlẹ Ondo.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Obìnrin ló ni ilé àti àdúgbò fún ìdí èyí wọ́n lè ṣe ìlú dáadáa'

Iṣana pẹlu awọn ohun ti ẹgbẹ oselu PDP pin fun awọn eniyan saaju idibo gbogboogbo lọdun 2015.

Image copyright Facebook
Àkọlé àwòrán Ni ọjọ keje, osu keje, ọdun 2013, Raji Fashola lasiko to si wa ni ipo gomina Eko lọ ra ọgẹdẹ sisun ti wọn n pe ni boli lasiko ipolongo.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionMurphy Elégungun Rọba: Mo fẹ́ di ẹnití egungun rẹ rọ jùlọ ní àgbáyé
Image copyright NAiraland
Àkọlé àwòrán Lọdun 2015, a ri awọn aworan to jẹyọ pẹlu gaari, ẹpa ati ṣuga pẹlu asia ẹgbẹ oṣelu PDP ti wọn pin fun awọn eniyan.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption2019 Elections: Èrò àwọn ọmọ Nàíjíríà se ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lóri ètó àlùfáà tàbí ìmámù lásìkò ìbò
Image copyright FACEBOOK
Àkọlé àwòrán Alaga ẹgbẹ oselu APC, Adams Oshiomole ati Godwin Obaseki lọdun 2016 ni aworan jade ti wọn n jẹ agbado sise laarin igboro.

Ẹgbẹ oselu APC pin iwe pẹlu asia ẹgbẹ pẹlu aworan aarẹ Buhari ati igbakeji Osinbajo lasiko idibo gbogboogbo lọdun 2019.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionOsinbajo: Ikẹnnẹ yẹ kó jẹ́ Mẹ́kà òṣèlú ni