Àyájọ́ èdè abínibí: Ǹ jẹ́ o ní ìfẹ́ sí èdè abínibí rẹ?

Àyájọ́ èdè abínibí: Ǹ jẹ́ o ní ìfẹ́ sí èdè abínibí rẹ?

Loni yii ni ayajọ ede abinibi jake jado agbaye.

Ajọ isọkan orilẹede agbaye lo ya ọjọ Kọkanlelogun osu Keji ọdọọdun sọtọ gẹgẹ bii ọjọ ta maa se agbelarugẹ ede abinibi wa jake jado agbaye,

Idi ree ti ileesẹ BBC naa, ninu fidio yii, fi kọ wa ba se lee sọ pe a nifẹ ede abinibi wa ni ede marun ọtọọtọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Awọn ede naa ni ede oyinbo, Pidgin, Igbo, Yoruba ati Afrique.

O ya, wo bo se lee sọ pe o nifẹ ede abinibi rẹ ni awọn ede marun naa.