Farah Khaleck tó ń mórí ènìyàn wú ní àìsàn ara bíbó láti ọdun mẹrinla.

Farah Khaleck tó ń mórí ènìyàn wú ní àìsàn ara bíbó láti ọdun mẹrinla.

Àìsàn ara bíbó (scleroderma) ti kò gbóógùn tó ń bá Arabinrin Farah Khaleck fínra láti ọdún mẹ́rìnlá, ko se idiwọ fun lati jẹ ohun iwuri fun awọn eniyan.

Arabinrin naa, tii se ọmọ bibi ilẹ India sọ wi pe, oun ko fẹran ara oun nigba ti aisan naa kọkọ bẹrẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Lẹyin naa lo parọwa fun ara rẹ, to si bẹrẹ si ni gbe igbe aye akinkanju.

Ninu ọrọ rẹ, o ni "Mo n lo fila ibori hijab mi, mo si fẹran ara mi lẹyin ti mo wo ara mi ninu jigi".