Ṣé o mọ̀ pé irun jẹ́ ọ̀nà kan láti fi dá omidan mọ̀?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Myanmar: kékeré ni wọ́n ti n kọ́ àwọn ọmọ nípa ọ̀nà oge ṣiṣe

Irun wa maa n ṣafihan boya sisí ni wa tabi bẹẹkọ.

Bayii ni a n ṣe nile wa, eewọ ibo mii ni ọrọ aṣa jẹ kaakiri agbaye.

Ilu Mayanmar ni Asia ni a ti ri irun ṣiṣe gẹgẹ bii ọkan lara ọna ti obinrin fi le pe ọkunrin.

Iwadii fihan pe irufẹ sitaili irun ti awọn ọdọmọbinrin wọnyii ba ṣe ni yoo fihan boya wọn n wa ọkọ tabi bẹẹ kọ.

Aṣa yii jẹ itẹwọgba kaakiri agbegbe yii ni eyi to n sọ fun awọn ọkunrin boya omidan tabi adelebọ ni obinrin ti wọn pade laini lati beere.

Related Topics