Ojude Ọba 2019: Àwọn èèkàn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti péjú fún ayẹyẹ ojúde Ọba

Àkọlé àwòrán Ojude Oba tí ọdún yìí ti gbéra sọ pẹ̀lú oníruuru àwọn aṣọ alárànbara yorùba to ń wúni lóri, Awọn ẹgbẹ́ Tobalàṣẹ obinrin rèé nínú àṣọ okè aláwọ̀ ewé
Àkọlé àwòrán Gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Gbobaniyi lókùnrin àti lóbìrin ló ti lọ ki ọba aláde lóri ìjòkò
Àkọlé àwòrán Lẹ́gbẹ́ lẹ́gbẹ́ ni gbogbo àwọn ti wọ́n péju síbi ayéyé Ojude Oba tí ọdún 2019
Àkọlé àwòrán Tokùnrin tobinrin ló wọsọ ìgbà níbi àyẹyẹ ojude oba tọdún yìí, Ẹgbẹ́ Bọbakẹ́yẹ Ọkunrin ni àwọn yìí
Àkọlé àwòrán Tarúgbó tomidàn ló wà nibi àyẹyẹ yìí, gbogbo oju wọ́n lo gúrégé pèlú, àwọn ẹgbẹ́ bọ́bakẹ́yẹ obinrin rèé
Àkọlé àwòrán Gbogbo àwọn olóyè àti èèkàn ìlú ló péjú
Àkọlé àwòrán Kìí ṣe àwọn ẹgbẹ́ gbẹ́ jọdá nìkàn ló péju, àwọn ọdọ náà jáde wá láti yẹ́ àṣ]a ìbílẹ̀ sí
Àkọlé àwòrán Aláàfin Ọyọ, ikú bábá yèyé, Ọba Lamidi Adeyemi náà péjú síbi ayẹyẹ ojúde Oba ní'lú Ijebu
Àkọlé àwòrán Gómínà ìpínlẹ̀ Ogun, Dapo Abiodun àti Awùjalẹ̀ Ijẹ̀bú Ọba Sikiru Adetona
Àkọlé àwòrán Gómìnà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Ogun, Ọtunba Gbẹnga Daniels
Àkọlé àwòrán Ẹgbẹ́ Bọ́baguntẹ ilẹ̀ Ijẹbu
Àkọlé àwòrán Gbogbo ojú tó ti ríra típẹ tún ni àànfàni láti ṣe "Ẹ k;u àti"
Àkọlé àwòrán Ẹgbẹ́ Obafunwaji Obinrin Adedoyin rèé nínú aṣọ ofi aláwọ̀ búlù
Àkọlé àwòrán Ẹgbẹ́ Tobalaṣẹ Ọkunrin náà ko gbẹ́yìn
Àkọlé àwòrán Gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Gbobaniyi lókùnrin àti lóbìrin ló ti lọ ki ọba aláde lóri ìjòkò