Valentine: Ọkùnrin ní kí obìnrin má fún àwọn ní àwọ̀tẹ́lẹ̀ mọ́ bíi ẹ̀bùn ọjọ́ olólùfẹ́

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionValentine: Ọkùnrin ní kí obìnrin má fún àwọn ní àwọ̀tẹ́lẹ̀ mọ́ bíi ẹ̀bùn ọjọ́ olólùfẹ́

Ọjọ Kẹrinla osu keji ọdọọdun ni awujọ agbaye maa n se ajọyọ ọjọ ololufẹ, eyi ti ko yọ orilẹede Naijiria silẹ.

Idi ree ti BBC Yoruba fi tọ tọkọtaya kan lọ lati mọ ero wọn nipa ayajọ ọhun.

Wọn salaye pe ọjọ naa wa lati fi ifẹ kan si gbogbo eeyan ni, kii se fun ọrẹbinrin abi ọrẹkunrin nikan.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Wọn wa rọ awọn obinrin lati fi òdòdó ṣe ẹ̀bùn ọjọ́ olólùfẹ́ fún ọkùnrin dípò ko gbà lati jẹ kó já òdòdó ara oun.