Tantra: Ìlànà yìí ló ń kọ́ wa láti fi èémí àti ìṣẹ́po ara gbádùn ìbálòpọ̀

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionTantra: Ìlànà yìí ló ń kọ́ wa láti fi èémí àti ìṣẹ́po ara gbádùn ìbálòpọ̀

Christiana, tii se oludanilẹkọ nipa ibalopọ lorilẹede Singapore, to jẹ ẹni ọgbọn ọdun, ni pẹlu ilana idanilẹkọ Tantra, a lee mu ara wa debi to ga julọ ninu ibalopọ.

Arabinrin ọmọ ilẹ Singapore naa sọ awọn ọna ti obinrin le gba lati le gbadun ibalopọ, pẹlu eemi ati awọn isẹpo ara lasan, eleyii ti o ni ko wọpọ ni awujọ wa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ẹ wo fidio naa fun ẹkunrẹrẹ alaye nipa igbadun ibalopọ nilana Tantra.