Covid-19 Vaccine Misinformation: Wo ìròyìn òfegè mẹ́jọ táwọn adarí ẹ̀sìn ń sọ nípa àbẹ́rẹ́ àjẹsára Coronavirus

Covid-19 Vaccine Misinformation: Wo ìròyìn òfegè mẹ́jọ táwọn adarí ẹ̀sìn ń sọ nípa àbẹ́rẹ́ àjẹsára Coronavirus

Yoruba ni ọrọ okeere, bi ko ba le ọkan, yoo din ọkan ni.

Bẹẹ ni ọrọ ri pẹlu abẹrẹ ajẹsara to n tako arun Coronavirus ti wọn se sita jakejado agbaye.

Oluwadi kan nipa abẹrẹ ajẹsara naa ni fasiti Washinton, Kolina Koltai ati akọroyin BBC se akojọpọ awọn iroyin ofege mẹjọ to lu igboro pa nipa abẹrẹ naa.

Gẹgẹ bi iwadi BBC naa se lọ, awọn asaaju ẹsin gbogbo yika agbaye atawọn adari awujọ lo n pin awọn iroyin ofege naa ka fawọn ọmọlẹyin wọn.

Wọn woye pe iru awọn iroyin eke yii lee da omi tutu sawọn araalu lọkan lati gba abẹrk ajẹsara naa.

Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ẹ wo fidio yii lati mọ koko iroyin ofege mẹjọ tawọn adari ẹsin naa n sọ nipa abẹrẹ ajẹsara to n dena arun Coronavirus.

Lara rẹ si ni pe ẹjẹ oyun inu ni awsn onimọ sayẹnsi po pọ lati se abẹrẹ naa, eyi to buru jai.