Òṣìṣẹ́ ètò ìlèra yóò jẹ́jọ́ lórí ikú Maradona

Diego Maradona

Oríṣun àwòrán, real Madrid

Òṣìṣẹ eto Ilera mẹjọ ni wọn yoo ma jẹjọ lori iku atamatase ọmọ orile-ede

Argentina, Diego Maradona latari bi wọn o ṣe kọbiara si eto Ilera rẹ Adajọ lọ pàṣẹ jẹjọ naa lẹyin ti awọn igbimo eto Ilera ni itọju Maradona ni awọn

ko lofin ninu.

Maradona, ẹni ogota ọdun ni osaliasi ni oṣu kokanla ọdun 2022 lẹyin niluu

Buenos Aires.

iwadi fihan pe Maradona tí n ri iwosan ni ile lẹyin ti wọn ṣe iṣẹ́ abẹ fun ninu oṣu

naa.

Lẹyin ọjo diẹ tí Maradona ku ni awọn agbejoro rẹ gbe igbimo kalẹ lati ṣe iwadi

nipa awọn dokita ati nusi to wa ni ìṣàkóso itọju rẹ.

Mario Baudry, Agbejoro fun ọkan lara awọn ọmọ ologbe naa, ni pe "ni asiko ti olojọ dẹ, ko ri iranlowo ẹnikẹ́ni."

"Kete ti mo rí nkan to fa okunfa ikú naa, ni mo ti ni ó ní ọwọ ko lofin ninu." Ọdún to lọ ní gbimo ẹlẹni ogún níye láti woo irúfé ikú to pa Maradona, ti iwadi si

fihan pe Maradona, ti o ba ri itọju to pe ye gba, ko ba iku. Ọjọ ti ijẹjọ naa ni o ti mo ṣùgbọ́n ti awọn òṣìṣẹ eto Ilera ba jẹbi ẹsun naa, wọn

yoo fi ẹwon ọdun medogbon gbara