Money ritual: Àwọn àṣà àtọ̀húnrìnwá ló fa títa ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ nítorí oògùn owó- Fayemi Elebuibon

Money ritual: Àwọn àṣà àtọ̀húnrìnwá ló fa títa ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ nítorí oògùn owó- Fayemi Elebuibon

Oniruuru ọna ẹrọ lawọn eeyan fi n ṣe etutu ọla. Eyi ko tilẹ yọ awọn ọdọ silẹ.

Amọṣa, BBC News Yoruba gbe ọrọ yii tọ awọn agbaagba ilẹ yii lọ.

Alaye wo ni Fayemi sọ nipa aajo ajé àti oogun owo?

Araba awo ilu Osogbo, Baba Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn ṣalaye ọrọ lori oṣolẹ, awure ati bi yoruba ṣe n lo wọn nigba iwaṣẹ.

Baba ni lootọ ni Yoruba n ṣe aajo owo, awure, oṣo o ni bi wọn ṣe n ṣe e o si ni awọn ti wọn n ṣee fun.