Ohun marun t'ejo n jẹ

Ejo ti o n gbe ekute mi Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Oṣiṣẹ ile iṣẹ ajọ JAMB sọ pe ejo gbe owo mi

Ejo jẹ ẹranko to maa n faya wọ, lati ẹka ẹranko to maa n jẹran nikan, ti o si le jẹ ajo bi ara rẹ.

Lara awọn ejo yi a maa dẹkun fun ẹran ti wọn ba fe paa jẹ, ti awọn ejo miran si ma a n wa ounjẹ jijẹ wọn lọ.

Ejo ma a n mi ounjẹ wọn ni nitori wọn ko ni eyin ti wọn ma fi jẹ ounjẹ wọn.

Ohun marun ti ejo n jẹ ni:

  1. Ẹyin adiyẹ
  2. Kokoro
  3. Ẹlẹdẹ
  4. Ẹja
  5. Owo ti o to miliọnu mẹrindinlogoji naira?

Ajọ JAMB fun osisẹ n'iwe lọ gbe'le ẹ

JAMB f'ọjọ kun asiko iforukosilẹ

Awọn nnkan miran wo ni o lero wipe ejo le jẹ? Kan siwa lori opo ikan ayelujara wa to fi mọ Facebook ati Instagram lori opo bbc.com/yoruba.