Awọn alatilẹyin Arsenal wipe Arsene Wenger gbọdọ lọ

Awọn alatilẹyin ẹgbẹ agbabọọlu Arsenal wipe Arsene Wenger gbọdọ kuro nipo rẹrẹ gẹgẹ bi adari ẹgbẹ naa.