Megabite: Ilé-ìwé ni mo ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ
Megabite: Ilé-ìwé ni mo ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ
Moruf Bello, tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Megabite, ti gba àwọn òbí ní ìmọ̀ràn pé kí wọn máse dí ọmọ wọn lọ́wọ́, tó bá ní ẹ̀bùn kan.
Lásìkò tó ń bá BBC Yòrùbá sọ̀rọ̀, Megabite ní ohunkohun tí òun bá rí ní àyíká òun, ni òun máa fi ń kọrin.