'Awọn kan n gba’bọde fun Super Eagles'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

'Awọn agbabọọlu Super Eagles kan n gba‘bọde fun Naijiria'

Alakoso ikọ agbabọọlu Super Eagles tẹlẹ ri, Adegboyega Onigbinde, sọ wipe ifura pe awọn agbabọọlu kan n gbabọde fun Naijiria lo faa, ti oun fi fun Vincent Enyeama ni anfaani ati mu ile fun Naijiria ninu idije ife ẹyẹ agbaye ti ọdun 2002.