Ìdíje Commonwealth: Nàijíría se ipò kejì ní table tennis

Ikọ̀ eléré ìdárayá ẹyin oríi tábìlì, Table tennis ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Image copyright NIGERIA TABLE TENNIS FEDERATION
Àkọlé àwòrán Nàijíría kò tíì gba góólù kankan ni ìdíje Commonwealth tó ń lọ lọ́wọ́.

Ikọ̀ eléré ìdárayá ẹyin oríi tábìlì, Table tennis ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kùnà àti gba àmì ẹ̀yẹ góòlù níbi ìdíje Commonwealth tó ńlọ lọ́wọ́ ní orílẹ̀-èdè Australia.Àmì ayò mẹ́ta sí òdo ni orílẹ̀èdè India fi gbẹyẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́.

Bode Abiodun, Jide omotayo pẹ̀lu Túndé Toríọlá ni wọ́n di ikọ̀ ẹyin oríi tábìlì, Table tenni,s ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mú nínú ìdíje náà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Nàìjíríà fàgbà han ikọ̀ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ìpele tó kángun si àṣekágbá pẹ̀lu àmì ayò mẹ́ta sí méjì.