Chelsea na Swansea 1-0 mole.

Aworan agbabọọlu ẹgbẹ Chelsea Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Giroud ati Hazard dawọ idunu pẹluFabregas lẹyin to je goolu keji ninu ifẹ̀sẹ̀wònse wọn.

Cesc Fabregas je góòlù àádọta rẹ láti ìgbà tó tí wá ni Premiership nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Chelsea àti Tottenham.

Pẹlu esi ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ yí, àmì méjì ló kù kí Chelsea fi ba Tottenham.

Iseju kẹrin ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà ni Chelsea ti jẹ pẹlu bi Eden Hazard ṣe gbà bóòlù sí Fabregas to si fi ẹsẹ òsì gbà wò inú ilé Swansea.

Pabo ni gbogbo akitiyan Swansea láti pa odo rẹ jasi.

Esi ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ yi tun mo sí pé ipenija àti ma fidiremi nínú Premiership tunbo peleke sí ní fún Swansea.

Related Topics