'Àwọn tó kájúẹ̀ ni Gernot Rohr pè'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Alukoro Super Eagles: Ọjọ́ kẹrin, osù kẹfà ni orúkọ yóò jáde

BBC Yorùbá bá Alukoro Super Eagles, Toyin Ibitoye sọ̀rọ̀ lórí orúkọ àwọn ikọ̀ tí yóò lọ sojú Nàíjíríà ní ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé tó ń bọ̀ ní osù kẹfà ní orílẹ̀èdè Russia.

Ò ní àwọn agbábọ́alù tó kájúẹ̀ ni Gernot Rohr pè lọ sí Russia 2018, tí yóó sì kéde ojúlówó orúkọ wọn ní ọjọ́ kẹrin, osù kẹfà.

Ibitoye tun yan pé, ifẹsẹ̀wọnsẹ̀ ọlọ́rẹ̀ẹ́-sọ́rẹ̀ẹ́ méjì ni Super Eagles yóò gbá, kí ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé tó bẹ̀rẹ̀.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: