Nigeria vs DR Congo: Báwo ni alẹ́ òní yóò ṣe rí?

Mikel Obi ati Arthur Masuaku
Àkọlé àwòrán Mikel Obi yóò kojú Arthur Masuaku ni Pọtá lálẹ́ òní

Nàìjíríà ati DR Congo yóò fàgbà han ara wọn láago márùn un ìrọ̀lẹ́ òní gẹ́gẹ́ bi agbẹnusọ Super Eagles ṣe sọ

Àgbéyẹ́wò àwọn ìgbà mẹ́fa sẹ́yìn ti ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà àti DR Congo ti pàdé awọn ikọ̀ miiran nínú ìdíje tó lè fún wa ni òye bí alé oni le ṣe lọ.

ÀTẸ ÌDÍJE TÓ TI WÁYÉ SẸYIN FÚN IKÒ AGBABỌỌLU MÉJÈÈJÌ

IRÚFÉ ÌDÍJE ỌJỌ TIDIJE NÁÀ WÁYÉ ÀWỌN TI WỌN JỌ PÀDÉ ÀBÁJÁDE ÌDÍJE
Kikopa ninu FIFA ipele kẹta tilẹ Adulawọ ọjọ kerin osu kesan ọdun 2017 Naijiria ati Cameroon 1-1 (ookan si ookan)
Kikopa ninu FIFA ipele kẹta tilẹ Adulawọ ọjọ keje, oṣu kẹwaa ọdun 2017 Naijiria ati Zambia 1-0 (ookan si odo)
Kikopa ninu FIFA ipele kẹta tilẹ Adulawọ ójó kẹwaa oṣu kọkanla ọdun 2017 Naijiria ati Algeria 1-1 (ookan si ookan)
Idije fun agbaye ọjọ kẹrinla oṣu kọkanla ọdun 2017 Naijiria ati Argentina 4-2 (mẹrin si meji)
Idije fun agbaye ọjọ kẹtalelogun oṣu kẹta ọdun 2018 Naijiria ati Poland 1-0 (ookan si odo)
Idije fun agbaye ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣu kẹta ọdun 2018 Naijiria ati Serbia 0-2 (odo si meji)
Idije fun agbaye ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣu kẹta ọdun 2018 DR Congo ati Tanzania 0-2 (odo si meji)
Kikopa ninu FIFA ipele kẹta tilẹ Adulawọ ọjọ kọkanla oṣu kọkanla ọdun 2017 DR Congo ati Guinea 3-1 (mẹta si ooka)
Kikopa ninu FIFA ipele kẹta tilẹ Adulawọ ọjọ keje oṣu kẹwaa ọdun 2017 DR Congo ati Libya 2-1 (meji si ookan)
Kikopa ninu FIFA ipele kẹta tilẹ Adulawọ ọjọ karun un oṣu kẹsan ódun 2017 DR Congo ati Tunisia 2-2 (meji si meji)
Kikopa ninu FIFA ipele kẹta tilẹ Adulawọ ọjọ kinni oṣu kẹsan ọdun 2017 DR Congo ati Tunisia 1-2 (ookan si meji)
Idije fun agbaye ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu kẹta ọdun 2017 DR Congo ati Kenya 1-2 (ookan si meji)

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: