Gbolahan Kabiawu: Fífi ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ ń dóòlà ẹ̀mí àwọn èèyàn

Gbolahan Kabiawu: Fífi ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ ń dóòlà ẹ̀mí àwọn èèyàn

Dokita Gbolahan Kabiowu to jẹ onimọ nipa ẹjẹ ati ayẹwo ara sọrọ lori pataki fifi ẹjẹ silẹ loorekoore.

O ni ẹjẹ ara dabi kanga ti wọn ni lati maa fà nigba gbogbo ki tuntun lè wọle.